bait (n)
|
ìwọ̀, ìdẹ, ìjẹ́ |
bake (v)
|
sè, yan, dín |
bakery (n)
|
ilé ìse àkàrà, ilé alákàrà, ilé àsè |
balance (n)
(physical)
|
ọgbọgba |
balance (n)
(remainder)
|
ìyókù |
balance (v)
|
wọ̀n lọ́gbọgba |
balcony (n)
|
àgbàlá, ọ̀dẹ̀dẹ̀, òde lókè ilé pẹ̀tẹ́sì, ọ̀ọ̀dẹ̀ |
bald (adj)
|
apárí, pípárí, àìṣelọ́ṣọ̀ọ́, àìnírunlórí |
ball (n)
|
ìṣù, ohun ìṣeré ọmọdé, bọ́ọ̀lù |
ballerina (n)
|
oníjó a fi téńté ọmọ ìka ẹsẹ̀ jó |
balloon (n)
|
ọkọ́ ófúrufú aláfẹ́fẹ́ gbígbóná |
ballot (n)
|
ìbò |
ban (n)
|
ìfòfin dè, ìfilọ̀ ní gban̄gba, ìgégùn-ún |
ban (v)
|
dádúró, fi-bú |
banana (n)
|
ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹrẹ |
band (n)
(music)
|
ẹgbẹ́ onílù tàbí bẹ̀m̀bẹ́ òyìnbó |
band (n)
(people)
|
ìpéjọ ọ̀pọ̀ ènìà, ẹgbẹ́ |
band (n)
(strip)
|
ọ̀já |
bandage (n)
|
ìrépé aṣọ ìfi di ọgbẹ́ |
bandit (n)
|
olè, alọ́nilọ́wọ́gbà, ọlọ́ṣà, aláìlófin |