Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

oak (n) igi apádò, igi óàkù
oar (n) àjẹ̀, òbèlè
occasion (n) àyè, ọ́nà, ìdí
occasionally (adv) lẹ́ẹ̀kọkan, láìṣègbàgbogbo, nìlàrenílàre
occupation (n) iṣẹ́, ìní, ìdawọ́bò, ìbùdó
occupy (v) gbé, ṣiṣẹ́, gba ipò, dawọ́bò, bùdó
occur (v) ṣẹ̀, ṣẹlẹ̀, hàn
occurence (n) (event) ìṣẹlẹ̀
ocean (n) òkun nlà, agbami òkun
October (n) oṣù kẹwàá ọdún
odor (n) òórùn, okiki
off (adv) (light) pa
offense (n) ẹ̀ṣẹ̀
offer (n) ẹbọ, ìfilọ̀
offer (v) fí-fún, fi-lọ̀, rúbọ
office (n) iṣẹ́, ibi iṣẹ́, ipò iṣẹ́, oyè
officer (n) (military) ọ̀gágun
official (adj) lábẹ́ àṣẹ, nípa agbára, oyè
official (n) oníṣẹ́
oil (n) epo, òróró, ọ̀rá