Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

wages (v) owó iṣẹ́, owó ọ̀yà
wagon (n) kẹ̀kẹ́ ẹrù
waist (n) ìbàdí, ìdí
wait (v) dúró, dúró dè, dúró tì, retí
waiter (n) adúró tini, agbawó oúnjẹ, adìgbàró
wake (v) jí, ṣe àìsùn, tají
walk (n) ìrìn
walk (v) rìn, fi ẹsẹ̀ rìn
wall (n) ògiri, ìgànná
wallet (n) àpò oúnjẹ, àpò owó
want (n) (lack) àìní, àbúkú, òfò, àìtó
want (n) (need) fífẹ́, fẹ́
want (v) (desire) fẹ́
want (v) (need) ṣe àìní, fẹ́, fẹ́-kù
watch (n) (guard) ẹ̀ṣọ́, ìṣọ́
watch (n) (time) agogo, aago
watch (v) (look) wò-ran
watch (v) (maintain) ṣe àkíyèsí bójútó
watch (v) (observe) ṣọ́, wò
world (n) ayé, aráyé