Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

each (adj) ọ̀kọ̀kan, olúkúlùkú
eager (adj) nítara, níwára
eagle (n) idì (ẹyẹ)
ear (n) etí, ṣirì-ọkà
earn (v) pa owó iṣẹ́, jẹ, ṣiṣẹ́ owó, rí-gbà, tọ́sí
earth (n) ayé, ilẹ̀, èrùpẹ̀
earthquake (n) ìrúké ilẹ̀, ilẹ̀ mímì, ìwàrìrì ilẹ̀
ease (n) ìrọra, àìnira, ìdẹra
east (n) ìlà òrùn, gàbasì
Easter (n) ọjọ́ àjínde Krístì, àgbèǹde
eastern (adj) nìlà-òrùn
eastwards (adj) lọ́nà ìlà-òrùn, níha ìlà-òrùn
easy (adj) rọrùn, láìṣòro, ní-rọrùn, láìnira
echo (n) gbohùngbohùn, àpèpadà
eclipse (n) àpapọ̀ òrùn àti òṣùpá ní àwọ̀sánmà, ìṣìjìbò, ìmúṣókùnkùn
ecology (n) ẹ̀kọ́ nípa ọ̀gbọgbà ayé
economic (adj) nípa ìṣúnná, ọrọ̀-ajé
economy (n) ìṣúnná, ìṣúnlò, ọrọ̀-ajé, mímọ owó tọ́jú
edge (n) ojú ohun èlò, etí nkan, ìgbátí, ojú ọ̀bẹ
edit (v) tún ìwé kíkọ ṣe fún títà, olótùú