kangaroo (n) | ẹranko afikùn gbọ́mọ rẹ̀ pọ̀n |
keep (v) | fi pamọ́, tọ́jú |
kennel (n) | ilé ajá |
key (n) | kọ́kọ́rọ́, ọmọ ìṣíkà, ọmọ àgàdàgodo, ìtumọ̀ |
kick (n) | ìtàpá |
kick (v) | tàpá |
king (n) | ọba |
kiss (n) | ìfẹnukonu |
kiss (v) | fi ẹnu konu |
kitchen (n) | ilé ìseńjẹ, ibi ìdáná |
knead (v) | pò |
knee (v) | orúnkún, eékún |
kneecap (n) | egungun eékún |
kneel (v) | kúnlẹ̀ |
knife (n) | ọ̀bẹ |
knight (n) | irú olóyè kan |
knit (v) | fi ọwọ́ hun, dàpọ̀ |
knob (n) | kókó |
knock (v) | lù, kàn, kànkùn |
knot (n) | kókó, ìdìjú, ìsolù |