Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

qualification (n) ìmúye, ẹ̀rí, ìjẹ́rìí ìwà
qualified (adj) ní ti ìmúye, ti ẹlẹ́rìí, ti ẹ̀yán
qualify (v) múyé, yán
quality (n) ìwà, agbára, ìrí, àwòmọ́
quantity (n) títóbi, ìwọ̀n, iye
quarrel (n) ìjà, asọ̀, gbólóhùn asọ̀, ariwo
quarrel (v) jà, sọ̀, ṣe gbólóhùn asọ̀, ṣawọ̀
quarrelsome (adj) tí o lè jà, oníjà, aláriwo
quarter (n) ìdámẹ́rin ohunkóhun, itún
quay (n) èbúté, ibi ìgúnlẹ̀ sí
queen (n) ayaba, oba obìnrin
query (n) ìbéèrè, èredí
question (n) ìbérè, iyèméjì
question (v) ṣe ìbérè, bi lérè
queue (n) títò
queue (v)
quick (adj) yára, láyè, tàrà, tètè
quiet (adj) dákẹ́, pẹ̀lẹ́, ìdákẹ́jẹ́, jẹ́jẹ́
quit (v) fi sílẹ̀, kọ̀ sílẹ̀, ṣe giri, lọ kúrò
quiz (v) dánwò, ṣe ìbérè