cabbage (n)
|
ẹ̀fó òyìnbó |
cabin (n)
|
yàrá inú ọkọ̀, yàrá, àgọ́ |
cabinet (n)
(government)
|
ìgbìmọ̀ ìjọba |
cabinet (n)
(storage)
|
àpótí ohun ọ̀ṣọ́ |
cable (n)
|
okùn tàbí ẹ̀wọ̀n ìdákọ̀ dúró |
cactus (n)
|
igi ọrọ́ |
café (n)
|
ilé ìjẹun |
caffeine (n)
|
èlò kíkorò inú obì, èlò ìmu kánilára, èlò ìrúsókè ara |
cage (n)
|
ilé ẹiyẹ, àgọ̀, kuku |
cake (n)
|
akara didun oyinbo, ole, moinmoin |
calcium (n)
|
ògùn ìmún egungun lágbára, ohun éló pàtàkì tí mbẹ nínú ilẹ̀ |
calculate (v)
|
ṣírò, kà |
calculation (n)
|
ìṣirò, kíkà |
calculator (n)
|
ẹ̀rọ ìṣirò |
calendar (n)
|
ìwé ìkaye oṣù/ọ̀sẹ̀/àti ọjọ́ nínú ọdún |
calf (n)
(animal)
|
ọmọ màálù |
calf (n)
(leg)
|
iṣu ẹsẹ̀ |
call (n)
(contact)
|
ìpè |
call (n)
(telephone)
|
bíbásọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ, pípè lórí ẹ̀rọ ìsọ̀rọ̀gbésì |
call (v)
(contact)
|
pè |