Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

parrot (n) aíyèkòótọ́
part (v) pín, ya, la irun orí
pass out (v) dá kú, pín
penis (n) okó
perform (v) ṣe, mú-ṣe
plant (n) (factory) ilé iṣẹ́, ilé òwò, ibití a tí nṣe ohun títà
plant (n) (object) ewéko, ewébẹ̀, ohun ọ̀gbìn
plead (v) (law) bẹ̀bẹ̀ fún, tọrọ ìdáríjì, gbẹjọ́rò
poor (adj) tálákà, aláìní, alábòsí, òtòṣì, alábùkù
pork (n) ẹran ẹlẹ́dẹ̀
praise (n) iyìn, ìyìn lógo
praise (v) yìn, fí iyìn fún
pray (v) gbàdúrà, bẹ̀bẹ̀, tọrọ, kírun
prayer (n) àdúrà, ẹ̀bẹ̀, ìtọrọ, ìkírun, ìbẹ̀bẹ̀
preach (v) wàásù
precaution (n) ìtètè fura, ìtètè kíyèsí láìkáàbámọ̀
pregnancy (n) oyún
pregnant (adj) lóyún, ní ọgbọ́n, kún fún
punish (v) jẹ níyà, ṣẹ́ níṣẹ̀ẹ́
punishment (n) ìyà, ìjìyà, ìjeníyà