Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

label (n) ìwé ìsàmì
labor (n) (medical) ìrọbí
labor (n) (work) iṣẹ́, làálàá
lamp (n) fìtílà, àtùpà
land (n) ilẹ̀
left (adj) òsì
leg (n) ẹsẹ̀
lemon (n) òrom̀bó kíkan
lend (v)
lethal (adj) eléwu
load (n) ẹrù
love (n) ìfẹ́
love (v) fẹ́, fẹ́ràn
lucky (adj) ní orí rere
luggage (n) ẹrù
lumber (n) gẹdú, pákó lílà
lump (n) ìṣù
lunch (n) onjẹ ọ̀sán
lust (n) (desire) àgbèrè, ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́
lust (n) (seọual) àgbèrè