Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

yacht (n) ọkọ̀ ojú omi fún fàájì
yard (n) (area) àgbàlá
yawn (n) yíyán
yawn (v) yán
year (n) ọdún, oṣù méjìlá
yeast (n) ìwúkàrà, ọ̀ṣẹ̀
yell (v) ké ramúramù, bú, kọ
yellow (adj) pupa rúsúrúsú, bí àwọ̀ ìyeyè
yes (n) (response) ẹn, bẹ́ẹ̀ni, òótọ́
yesterday (adv) àná, lánàá
yet (adv) síbẹ̀, síbẹ̀síbẹ̀, bí ó tilẹ̀ rí bẹ́ẹ̀
yield (n) èrè, ẹ̀san iṣẹ́, ìkórè
yield (v) (crop) so, múwá, san, yọ̀ọ̀dà
yogurt (n) wàrà
yolk (n) (egg) pupa ẹyin
young (adj) ṣọmọdé, ṣọ̀tun, ṣọmọdan
your (adj) (one person) tìrẹ
your (adj) (several) tiyín
youth (n) (people) ọ̀dọ́, ọ̀dọ́mọdé, èwe, ọ̀pẹ̀ẹ̀rẹ̀
youth (n) (time) èwe