Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

vacancy (v) ààyè, àfo, òfúrufú
vacant (adj) lófo, l'ásán, láìrọ́pò, ṣófo
vacate (v) parẹ́, fi àyè sílẹ̀ fún, sọ di asán , ṣe òfò, fi ipò sílẹ̀
valid (adj) nípá
valuable (adj) níyelórí, lérèlórí, oníyebíye, lówólórí
veil (n) ìbojú
verb (n) ọ̀rọ̀ ìṣe
verse (n) ẹsẹ, ìwọ̀n tí a pín orí ìwé sí
veto (n) agbára kíkọ̀
victory (n) ìṣẹ́gun, ìborí
village (n) ìletò, abúlé
violate (v) bà jẹ́, pa-lára, rú, ṣẹ̀ sí
vocabulary (n) ìwé ìkójọ ọ́rọ́, ìwè gbédègbẹ́yọ̀
void (adj) (law) ṣòfò, asán
void (n) àlàfo, àfo
volume (n) (book) àpò-ìwé, ìwé
volume (n) (size) ọ̀pọ̀
volume (n) (sound) ariwo
vomit (v) bì, pọ̀-jáde
vote (n) ìbò, ìlohùnsí, yíyàn, ohùn