Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

habit (n) ìwà, ìṣe, bárakú, ìwọṣọ
hail (n) òjò dídì, yìnyín
hair (n) (body) irun ara
hair (n) (head) irun orí
haircut (n) irungígẹ̀
hairdresser (n) (f) onídìrí
hairdresser (n) (m) afárun
hairstyle (n) irú irun ígẹ̀ tàbi dídì lóríṣiríṣi
hairy (adj) onírun yẹtuyẹtu
half (adj) ìdajì, àbọ̀
half (n) àbọ̀, ìdáméjì
half-breed (n) ẹnití àwọn òbi rẹ̀ wá láti ẹ̀yà ọ̀tọ̀tọ̀, ṣeku-ṣẹiyẹ, kòṣeku-kòṣẹiyẹ
hall (n) yàrá ńlá
hallucination (n) ìṣújú
halve (v) dá sí méjì, pín sí méjì
ham (n) itan ẹlẹ́dẹ̀ oníyọ̀
handful (adj) ìkúnwọ́
handshake (n) ìbọwọ́
handsome (adj) dára, lẹ́wà
handwriting (v) ìkọ̀wé