Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

handy (adj) rọrùn, nítòsí
hang (v) gbé kọ́, fikọ́
hangar (n) ilé ìfipamọ́ ọkọ̀ òfúrufú
happen (v) ṣẹlẹ̀, ṣe
happiness (n) inúdídùn, àlàáfíà, ìrọra, ayọ̀
harbor (n) èbúté ọkọ̀
hard (adj) nira, le, ṣòro
hardship (n) ìṣòro, ìnira
hare (n) ehoro
harem (n) ilé ẹlẹ́hàá
harm (n) ìpalára, ibi, ìbàjẹ́
harm (v) palára
harmful (adj) nípàlaára
harmless (adj) láìléwu, láìnípalára
harmony (n) ìṣedédé, ìrẹ́pọ̀, ìbárẹ́
harness (n) ìjánu ẹṣin
harsh (adj) (difficult) líle, le
harvest (n) ìkórè
haste (n) ìyára, ìkánjú, àìfarabalẹ̀, àìgbéjẹ́
hat (n) àkẹtẹ̀, ate