Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

hatch (n) yínyín, pípa ọmọ nínú ẹyin
hatch (v) yín, pa ọmọ nínú ẹyin
hatchet (n) àáké
hate (n) ìkórira, ìrira
hate (v) kórira
hateful (adj) kún fún ìrira
haul (v) gbé, fà, wọ́

heal (v) wòsàn, mú lára dá, wòjiná