Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

udder (n) ọmú ẹranko, ọmú màálù
ugly (adj) burẹ́wà, lábùkù, láìlẹ́wà
ulcer (n) egbò, oju/ojuju tí ńrà
underline (v) fa ilà sí labẹ́, sàmì ìfiyèsí ọ̀rọ̀
undermine (v) pa ìpilẹ̀ run, jìn lẹ́sẹ̀, wà nísàlẹ̀
underneath (adv) nísàlẹ̀, labẹ́
underpass (n) ọ̀nà abẹ́ títì
understand (v) mọ̀, yé, gbédè
understandable (adj) ti mímọ̀, ti yíyé
understanding (adj) ti òye
understatement (n) àìwítán
undertaking (n) ìdáwọ́lé
underwater (adj) lábẹ́ omi, nínú omi
underwear (n) àwọ̀tẹ́lẹ̀
undesirable (adj) àìwuni, tí kò wuni, tí a kò fẹ́ ní
uneducated (adj) láìlẹ́kọ̀ọ́
uniform (n) aṣọ ẹgbẹ́ kan, ìṣọ̀kan
unify (v) sọ di ọ̀kan, ṣe-sọ́kan, ṣe lọ́kan
university (n) ilé ẹ̀kọ́ gíga, yunifásítì
unjust (adj) láìṣòótọ́