Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

rabbi (n) olùkọ́ òfin Júù, olùkọ́ni
rabbit (n) ehoro onírun
rabies (n) àìsàn ìyawèrè ajá
raccoon (n) ẹranko bí ọ̀yà
rag (n) àkísà
rage (n) ìrunú, ìbínú
rain (n) òjò
ram (n) àgbò, ràgò
ramp (n) ọ̀nà gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ onípákó
ranch (n) oko ẹran-ọ̀sìn
rape (v) fi ipá bá obìnrin lò
rapid (adj) yára, kánkán
rapture (n) ayọ̀ púpọ̀, ayọ̀ ayọ̀jù
rattle (v) pariwo, mí pẹkẹpẹkẹ, kígbe
razor (n) abẹ ìfárí
razor blade (n) abẹ
rectify (v) tún ṣe, mú bọ́ sípò
recuperate (v) sọjí, mú bọ̀ sí ipò
recurrence (n) ìpadà
red (adj) pọ́n, pupa