| mad (adj) | ṣiwèrè, bíbàjẹ́ orí, asínwín |
| maggot (n) | ìdin |
| magic (n) | idán |
| make (v) | ṣe, dá |
| man (n) | ọkùnrin, ènìà |
| many (adj) | púpọ̀, pọ́, ọ̀pọ̀lọpọ̀ |
| march (n) |
oṣù kẹta ọdún yíyan àwọn ọmọ ogun |
| march (v) | rìn lẹ́sẹsẹ, yan |
| mare (n) | abo ẹ́ṣin |
| mark (n) | àmì orin, àpá |
| market (n) | ọjà |
| meet (v) | pàdé, kò lójú, kò lọ́nà, péjọ |
| melt (v) | yọ́ |
| mend (v) (repair) | tún-ṣe, mú-sàn |
| mercy (n) | àánú, ìyọ́nú |
| mill (n) | òlọ̀, ẹ̀rọ |
| mill (v) | lọ̀, rọ |
| mine field (n) | pápá ọta ìhámọ́lẹ̀ fún ìpalára ọ̀tá |
| mouth (n) | ẹnu |
| music (n) | orin |