sabotage (n) | ìjìn lẹ̀sẹ̀, ìmọ̀ọ́mọ̀ bíba ohun ẹlòmíràn jẹ́ ní kọ̀ọ̀kọ̀, ọ̀tẹ̀ |
sack (n) | àpò ńlá, akalambì |
sacrifice (n) | ẹbọ |
sacrifice (v) | rúbọ, ṣẹbọ, fi sílẹ̀ |
sad (adj) | binújẹ́, fajúro |
salt (n) | iyọ̀ |
salute (n) | ìkínni, ìkí |
salute (v) | kí |
sand (n) | iyanrìn, iyẹ̀pẹ̀, yanrìn |
savage (adj) | níkà, rorò |
save (v) (money) | fi pamọ́ |
save (v) (person) | yọ nínú ewu |
savings (n) (money) | ìfowópamọ́ |
saw (n) | ayùn |
saw (v) | rẹ́-igi, yùn, rí |
say (v) | wí, sọ |
saying (n) | wíwí, sísọ, ọ̀rọ̀ sísọ |
scab (n) | èpo, èpà |
scalp (n) | agbárí |
scar (n) | àpá ojú, àpá egbò, àléébù |