Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

baboon (n) ọ̀bọ lágídò, ìnàkí, irò
baby (n) ọmọ, ọmọ-ọwọ́, ọmọ-jòjòló
bachelor (n) àpọ́n
back (adj) ẹ̀hìn, tẹ̀hìn
back (adv) lẹ́hìn
back (n) (body) ẹ̀hìn
back (n) (location) ẹ̀hìn ọgbà
back (n) (support) tìlẹ́hìn, pọ̀n sẹ́hìn, rànlọ́wọ́
backbone (n) egungun ẹ̀hìn
background (n) ìpìlẹ̀, ipó ẹ̀hìn
backpack (n) àpamọ́ ìwé ọmọ iléwèé
backwards (adv) ìfàsẹ́hìn
bacon (n) ẹran ara ẹlẹ́dẹ̀ tí a fi iyọ̀ sí
bacteria (n) kòkòrò àìsàn
bad (adj) burú, burúkú, ṣàìdára
badge (n) àmì
baffle (v) dà-rú, sọ-dasán, tàn-jẹ
bag (n) àpò, ọ̀kẹ́
baggage (n) ẹrù
baggy (adj) ṣò, ṣíṣò