Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

ice (n) yìnyín, omi dídì
ice cream (n) wàrà dídì aláàdúùn
idiom (n) ẹ̀sọ ọ̀rọ̀
idle (adj) lẹ, áìṣiṣẹ́
idol (n) ère, òrìṣà
idolize (v) kẹ́, sọdòrìṣà
image (n) àwòrán, eré
imagine (v) fojú inú wò, rò, gbèrò
imitate (v) tẹ̀lé, ṣe àfarawé, farawé, sínjẹ
impulsive (adj) aláìnítẹ̀ẹ́nú, lágbára ìrọ́lù, àìfarabalẹ̀
inability (n) àìnípa, àìlágbára
inaccessible (adj) láìlèsúnmọ́, láìlèlàkọjá
inaccurate (adj) láìpe, láìkàpé, níṣìṣe
inactive (adj) láìṣe nkan, lẹ, láìṣIṣẹ́
inadequate (adj) láìtó, láìtóǹkan
irrigate (v) bomi rin
isolate (v) dá wà, dágbé, yà sọ́tọ̀, lé sọnù
itch (n) ìhúnra, ìṣáká, ifọ́n, kúrúnà
itch (v) húnra
itinerary (n) ìwé ètò ìrìnàjò