false (adj) | láìṣòótọ́, ní aiyédèrú, láìṣòtítọ́ |
fame (n) | òkìkí |
fuel (n) | ohun ìdáná, igi, ẹyìn |
fulfil (v) | mú ṣẹ |
fulfilment (n) | ìmúṣẹ, àmúṣe |
full (adj) | kún |
fumes (n) | èéfín, oru |
fun (n) | iré, ìṣiré, ẹ̀fẹ̀, àwàdà |
function (n) | ìlò, agbára, òye |
function (v) | ṣe, lò |
fund (n) | owo ìlélẹ̀, ìkójọpọ̀ owó |
fundamental (adj) | ti ìpilẹ̀ṣẹ̀, pàtàkì |
funeral (n) | ìsìnkú |
fungus (n) | olú, olú ehù igi |