abstract (adj) | àfòyemọ̀ |
absurd (adj) | ṣàìbọ́gbọ́nmu |
abundance (n) | ọ̀pọ̀ |
abundant (adj) | lọ́pọ̀lọpọ̀, jiwinni |
abuse (n) | èébú, àbùkù, ìlòlọ́nàìtọ́ |
abuse (v) | lòlọ́nàìtọ́, bú, lò nílòkulò, pèlórúkọkórúkọ |
abusive (adj) | èébú, ti èébú |
academic (adj) | àjẹmọ́ akadá |
academy (n) | ilé ẹ̀kọ́ gíga, ilé ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ |
accelerate (v) | mú yára, mú lọ síwájú |
acceleration (n) | ìyára |
accelerator (n) | ohun imúyára |
accent (n) (language) | àmì ohùn |
accept (v) | gbà, tẹ́wọ́gbà |
acceptable (adj) | gbígbà, títẹ́wọ́gbà |
acceptance (n) | ìtẹ́wọ́gbà |
access (n) | àyè, ọ̀nà |
accessible (adj) | fùn láyè |
accessories (n) | àwọn èròjà |
accessory (n) | èròjà |