Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

accident (n) èṣì, àgbákò, jàmbá, àdébá
accidental (adj) kíkàgbákò, jàmbá
accidentally (adv) láìròtẹ́lẹ̀
accommodate (v) fùn láyè
accommodation (n) ilé gbígbé, àyè
accompaniment (n) ìbánikẹ́gbẹ́, àjọrìnpọ̀
accompany (v) bá-lọ, bá-rìn, bá-kẹ́gbẹ́
accomplish (v) ṣe parí, ṣe-tán, ṣe àṣepé
accomplishment (n) àṣetán, ìṣeparí, ìṣepé
accordingly (adv) nítorínáà, bẹ́ẹ̀gẹ́gẹ́
accordion (n) dùrù afọwọ́tẹ̀, dùrù àfọwọ́lé
account (n) (bank) owò àpamọ́, ìṣirò, ìkàsí
accountable (adj) ṣe ìkàsí, dálẹ́bi
accrue (v) èrè, èlé, dá-lé
accumulate (v) kójọ, dá-lé
accumulation (n) ìkójọpọ̀, àdálé, àkànmọ́
accuracy (n) ìṣegẹ́gẹ́, ìṣedédé
accurate (adj) déédé, pé ṣánsán
accusation (n) ìbáwí, ẹ̀sùn, ìfisùn
accuse (v) fisùn, kà sí lọ́rùn