Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

glove (n) ìbọwọ́
glow (v) gbóná janjan
greed (n) ìwọra, ojúkòkòrò, awun
greedy (adj) níwọra, lójúkòkòrò, láwun
green (adj) aláwọ̀ ewéko, aláwọ̀ ọ̀bẹ̀-òdò, àìpọ́n, àìdẹ̀, tútù, ọbẹdò
greenhouse (n) ilé ìtọ́jú ohun ọ̀gbìn
greet (v) kí, yọ̀mọ́
greeting (n) ìkíni, ìyọ̀mọ́ní
grenade (n) ohun èlò ìjagun, ẹtù ìfọwọ́jù
grey (adj) tí ó lí àwọ̀ dúdú fẹ́rẹ́
grief (n) ìbanújẹ́, ìkáànú, ẹ̀dùn
grievance (n) ohun ìbanújẹ́, ẹ̀dùn, ohun tí ó mú ìbínújẹ́ wá
grieve (v) bànínújẹ́, dùn, mú ní kẹ́dùn
grill (v) fìró ẹ̀mí ẹni, dánwò, yan onjẹ lórí iná
grim (adj) korò, rorò
grime (n) èérí
grin (n) ẹ̀rín àìdénú
grin (v) rẹ́ẹ̀rín akọ, rẹ́ẹ̀rín ẹ̀gàn
grind (v) lọ̀, pọ́n
grip (n) ìgbámú, ìgbọwọ́