Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

grip (v) gbámú, dìmú ṣinṣin
groan (n) ìkérora, gbígbin
groan (v) kérora, kédàárò, gbin
groceries (n) ọjà, èèlò
groin (n) kòtò itan
groom (v) apoko ẹṣin, olùtọ́jú ẹṣin, ọkọ-ìyàwó
groove (n) ihò ìtẹ̀bọ̀
ground (n) ilẹ̀, ìdílé, ìpìlẹ̀, orísun
groundwork (n) ìpìlẹ̀
group (n) àkójọpọ̀, ìdìpọ̀, òkìtì
group (v) kójọpọ̀, dìpọ̀
grove (n) igbó kékeré, igbó ṣuru
grow (v) hù, so, dàgbà
growl (v)
growth (n) (development) ìdàgbàsókè
growth (n) (physical) dídàgbà ènìyìàn
growth (n) (tumor) tàn, ràn
grub (n) kòkòrò, ìdin
gruesome (adj) lẹ́rù, foniláyà, tìbẹ̀rù-bojo
grumpy (adj) oníkanra