Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

grunt (v) kùn bí ẹlẹ́dẹ̀
guarantee (n) onígbọ̀wọ́, ẹ̀rí
guarantee (v) ṣe ẹ̀rí
guard (v) ṣọ́, dábòbò
guard (v) (device) àbò, ẹ̀ro ìṣọ́ni
guess (n) alámọ̀, àbùsọ
guess (v) lámọ̀, rò sọ
guesthouse (n) ilé àlejò, ilé èrò
guidance (n) ìtọ́nà, ìfọ̀nàhàn
guide (v) tọ́ka, sìn, tọ́ sí ọ̀nà, fi ọ̀nà hàn
guidebook (n) ìwé ìtọ́nisọ́nà
guidelines (n) àwọn ètò ìtọ́nisọ́nà tàbí ìfọ̀nà han ni
guilt (n) ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀, ẹ̀ṣẹ̀
guilty (adj) jẹ̀bi, dálẹ́bi, ẹ́lẹ́ṣẹ̀
guitar (n) ohun ọnà orin olókùn títa
gulf (n) omi òkun tí ó yà wọ inú ilẹ̀
gullible (adj) tí ṣe ni ní ẹ̀gọ̀
gums (n) èrìgì
gun (n) ìbọn, àgbá
gunner (n) ayìnbọn, arọ́gbàá